Jẹnẹsisi 23:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọdún mẹtadinlaadoje (127) ni Sara gbé láyé.

2. Ó kú ní Kiriati Ariba, ní Heburoni, ní ilẹ̀ Kenaani, Abrahamu sọkún, ó sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀.

3. Nígbà tí ó yá, Abrahamu dìde níwájú òkú Sara, ó lọ bá àwọn ará Hiti, ó ní,

Jẹnẹsisi 23