Jẹnẹsisi 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu dá a lóhùn pé, “Ọmọ mi, Ọlọrun fúnrarẹ̀ ni yóo pèsè, àgbò tí a óo fi rú ẹbọ sísun náà.” Àwọn mejeeji tún ń bá ìrìn àjò wọn lọ.

Jẹnẹsisi 22

Jẹnẹsisi 22:6-17