Jẹnẹsisi 22:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu gbé igi ẹbọ sísun náà lé Isaaki, ọmọ rẹ̀ lórí, ó mú ọ̀bẹ ati iná lọ́wọ́. Àwọn mejeeji jọ ń lọ.

Jẹnẹsisi 22

Jẹnẹsisi 22:3-7