Jẹnẹsisi 22:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu bá pada tọ àwọn ọdọmọkunrin rẹ̀ lọ, wọ́n bá jọ gbéra, wọ́n pada lọ sí Beeriṣeba, Abrahamu sì ń gbé ibẹ̀.

Jẹnẹsisi 22

Jẹnẹsisi 22:12-24