Jẹnẹsisi 21:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe dá majẹmu ní Beeriṣeba. Abimeleki ati Fikoli, olórí ogun rẹ̀, sì pada lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Filistia.

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:31-34