Jẹnẹsisi 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki bá dá a lóhùn, ó ní “N kò mọ ẹni tí ó ṣe bẹ́ẹ̀, o kò sọ fún mi, n kò gbọ́ nǹkankan nípa rẹ̀, àfi bí o ti ń sọ yìí.”

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:25-32