Jẹnẹsisi 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wà pẹlu ọmọ náà, ó dàgbà, ó ń gbé ninu aginjù, ó sì mọ ọfà ta tóbẹ́ẹ̀ tí ó di atamátàsé.

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:12-23