Jẹnẹsisi 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sara lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan fún Abrahamu lẹ́yìn tí ó ti di arúgbó, ní àkókò tí Ọlọrun sọ fún un.

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:1-12