Jẹnẹsisi 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun tọ Abimeleki wá lóru lójú àlá, ó sì wí fún un pé, “O jẹ́ mọ̀! Ikú ti pa ọ́ tán báyìí, nítorí pé obinrin tí o mú sọ́dọ̀, aya aláya ni.”

Jẹnẹsisi 20

Jẹnẹsisi 20:2-4