Jẹnẹsisi 20:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé, arabinrin mi ni nítòótọ́, bí ó ṣe jẹ́ nìyí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ìyá kan náà ni ó bí wa, ọmọ baba kan ni wá kí ó tó di aya mi.

Jẹnẹsisi 20

Jẹnẹsisi 20:5-18