Jẹnẹsisi 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA Ọlọrun bù ninu erùpẹ̀ ilẹ̀, ó fi mọ eniyan. Ó mí èémí ìyè sí ihò imú rẹ̀, eniyan sì di ẹ̀dá alààyè.

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:1-15