Jẹnẹsisi 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún ọjọ́ keje yìí, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ọjọ́ náà ni ó sinmi ninu gbogbo iṣẹ́ ìṣẹ̀dá tí ó ti ń ṣe bọ̀.

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:1-13