Jẹnẹsisi 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà OLUWA Ọlọrun kun ọkunrin yìí ní oorun àsùnwọra, nígbà tí ó sùn, Ọlọrun yọ ọ̀kan ninu àwọn egungun ìhà rẹ̀, ó sì fi ẹran dípò rẹ̀.

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:11-25