Jẹnẹsisi 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà OLUWA Ọlọrun sọ pé, “Kò dára kí ọkunrin náà nìkan dá wà, n óo ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tí yóo dàbí rẹ̀.”

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:10-23