Jẹnẹsisi 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ odò kẹta ni Tigirisi, òun ni ó ṣàn lọ sí apá ìlà oòrùn Asiria. Ẹkẹrin ni odò Yufurate.

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:4-15