Jẹnẹsisi 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Odò kan ṣàn jáde láti inú ọgbà Edẹni tí omi rẹ̀ máa ń mú kí ọgbà náà rin. Lẹ́yìn tí odò yìí ṣàn kọjá ọgbà Edẹni, ó pín sí mẹrin.

Jẹnẹsisi 2

Jẹnẹsisi 2:3-12