Jẹnẹsisi 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pe Lọti, wọ́n ní, “Níbo ni àwọn ọkunrin tí wọ́n dé sọ́dọ̀ rẹ ní alẹ́ yìí wà? Kó wọn jáde fún wa, a fẹ́ bá wọn lòpọ̀.”

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:1-15