Jẹnẹsisi 19:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí àbúrò náà bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Bẹnami, òun ni baba ńlá àwọn ẹ̀yà Amoni títí di òní olónìí.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:35-38