Jẹnẹsisi 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó rọ̀ wọ́n gidigidi, wọ́n bá yà sí ilé rẹ̀, ó se àsè fún wọn, ó ṣe àkàrà tí a kò fi ìwúkàrà sí, wọ́n sì jẹun.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:1-10