Jẹnẹsisi 19:25 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì pa ìlú náà run ati gbogbo àfonífojì náà. Ó pa gbogbo àwọn tí wọn ń gbé àwọn ìlú náà run, ati gbogbo ohun tí ó hù lórí ilẹ̀.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:17-32