Jẹnẹsisi 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣe kíá, kí o sálọ sibẹ, nítorí n kò lè ṣe ohunkohun, títí tí o óo fi dé ibẹ̀.” Nítorí náà ni wọ́n ṣe sọ ìlú náà ní Soari.

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:18-24