Jẹnẹsisi 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé a ti ṣetán láti pa ìlú yìí run, nítorí ẹ̀sùn tí wọ́n fi ń kan àwọn ará ìlú yìí ti pọ̀ níwájú OLUWA, OLUWA sì ti rán wa láti pa á run.”

Jẹnẹsisi 19

Jẹnẹsisi 19:9-16