Jẹnẹsisi 18:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, ó ṣeéṣe pé aadọta tí mo wí lè dín marun-un, ṣé nítorí eniyan marun-un tí ó dín, o óo pa ìlú náà run?” OLUWA dáhùn pé, “Bí mo bá rí olódodo marundinlaadọta n kò ní pa ìlú náà run.”

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:23-33