Jẹnẹsisi 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bi Abrahamu pé, “Èéṣe tí Sara fi rẹ́rìn-ín, tí ó wí pé, ṣé lóòótọ́ ni òun óo bímọ lẹ́yìn tí òun ti darúgbó?

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:10-15