Jẹnẹsisi 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bukun un, n óo sì fún ọ ní ọmọkunrin kan láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, n óo bukun un, yóo sì di ìyá ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè, ọpọlọpọ ọba ni yóo wà lára atọmọdọmọ rẹ̀.”

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:13-22