Jẹnẹsisi 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọkunrin tí kò bá kọlà abẹ́ ni a óo yọ kúrò láàrin àwọn eniyan rẹ̀, nítorí pé ó ti ba majẹmu mi jẹ́.”

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:5-17