Jẹnẹsisi 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Majẹmu náà tí ó wà láàrin èmi pẹlu rẹ, ati atọmọdọmọ rẹ, tí ẹ gbọdọ̀ pamọ́ nìyí, gbogbo àwọn ọmọkunrin yín gbọdọ̀ kọlà abẹ́.

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:8-13