Jẹnẹsisi 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abramu di ẹni ọdún mọkandinlọgọrun-un, OLUWA farahàn án, ó sọ fún un pé, “Èmi ni Ọlọrun Olodumare, máa gbọ́ tèmi, kí o sì jẹ́ pípé.

Jẹnẹsisi 17

Jẹnẹsisi 17:1-7