Jẹnẹsisi 15:19-21 BIBELI MIMỌ (BM)

19. ilẹ̀ àwọn ará Keni, ti àwọn ará Kenisi, ti àwọn ará Kadimoni,

20. ti àwọn ará Hiti, ti àwọn ará Perisi, ti àwọn ará Refaimu,

21. ti àwọn ará Amori, ti àwọn ará Kenaani, ti àwọn ará Girigaṣi ati ti àwọn ará Jebusi.”

Jẹnẹsisi 15