Jẹnẹsisi 15:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n óo mú ìdájọ́ wá sórí orílẹ̀-èdè náà tí wọn yóo sìn. Àṣẹ̀yìnwá, àṣẹ̀yìnbọ̀, wọn yóo jáde kúrò níbẹ̀ pẹlu ọpọlọpọ dúkìá.

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:7-17