Jẹnẹsisi 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

pé, abẹ́rẹ́ lásán, n kò ní fọwọ́ mi kàn ninu ohun tí ó jẹ́ tìrẹ, kí o má baà sọ pé ìwọ ni o sọ mí di ọlọ́rọ̀.

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:19-24