Jẹnẹsisi 14:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Sodomu sọ fún Abramu pé, “Jọ̀wọ́, máa kó gbogbo ìkógun lọ, ṣugbọn dá àwọn eniyan mi pada fún mi.”

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:16-24