Jẹnẹsisi 14:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mẹlikisẹdẹki ọba Salẹmu náà mú oúnjẹ ati ọtí waini wá pàdé rẹ̀. Mẹlikisẹdẹki jẹ́ alufaa Ọlọrun Ọ̀gá Ògo.

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:14-23