Jẹnẹsisi 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọwọ́ wọn tẹ Lọti, ọmọ arakunrin Abramu tí ń gbé ní Sodomu, wọ́n mú un lẹ́rú, wọ́n sì kó gbogbo ẹran ọ̀sìn ati gbogbo ohun ìní rẹ̀ lọ.

Jẹnẹsisi 14

Jẹnẹsisi 14:6-21