Jẹnẹsisi 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọti tí ó bá Abramu lọ náà ní ọpọlọpọ ẹran ọ̀sìn ati agbo mààlúù ati ọpọlọpọ àgọ́ fún ìdílé rẹ̀ ati àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:1-6