Jẹnẹsisi 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mú kí àwọn ọmọ rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tí yóo fi jẹ́ pé, àfi ẹni tí ó bá lè ka iye erùpẹ̀ ilẹ̀ ni yóo lè kà wọ́n.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:6-18