Jẹnẹsisi 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan, ìyàn mú gidigidi ní ilẹ̀ Kenaani. Ìyàn náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí Abramu níláti kó lọ sí Ijipti, láti máa gbé ibẹ̀ fún ìgbà díẹ̀.

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:5-20