Jẹnẹsisi 11:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún gbé igba ọdún ó lé meje (207) sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Serugi, ó sì tún bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 11

Jẹnẹsisi 11:17-23