Jẹnẹsisi 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún gbé ọdún mẹtalenirinwo (403) sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Eberi tán, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 11

Jẹnẹsisi 11:8-19