Jẹnẹsisi 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹlu àtìlẹ́yìn OLUWA, Nimrodu di ògbójú ọdẹ, tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n máa ń fi orúkọ rẹ̀ súre fún eniyan pé, “Kí OLUWA sọ ọ́ di ògbójú ọdẹ bíi Nimrodu.”

Jẹnẹsisi 10

Jẹnẹsisi 10:1-13