Jẹnẹsisi 10:6-8 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ijipti, Puti ati Kenaani.

7. Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabita, Raama ati Sabiteka. Àwọn ọmọ Raama ni: Ṣeba ati Dedani.

8. Kuṣi ni baba Nimrodu, Nimrodu yìí ni ẹni kinni tí wọ́n mọ̀ ní akọni láyé.

Jẹnẹsisi 10