Jẹnẹsisi 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun pàṣẹ pé kí omi tí ó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́jọ pọ̀ sí ojú kan, kí ìyàngbẹ ilẹ̀ lè farahàn, ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:2-16