Jẹnẹsisi 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán, ó sì sọ òkùnkùn ní òru. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ kinni.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:2-8