Jẹnẹsisi 1:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wo gbogbo ohun tí ó dá, ó sì rí i pé wọ́n dára. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ kẹfa.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:28-31