Jẹnẹsisi 1:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún wí pé, “Mo ti pèsè gbogbo ohun ọ̀gbìn tí ń so èso ati igi tí ń so èso tí ó ní irúgbìn ninu fún yín láti jẹ.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:19-31