Jẹnẹsisi 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun pàṣẹ pé kí omi kún fún oríṣìíríṣìí ẹ̀dá alààyè, kí ojú ọ̀run sì kún fún àwọn ẹyẹ.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:12-25