Jẹnẹsisi 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

ayé rí júujùu, ó sì ṣófo. Ibú omi bo gbogbo ayé, gbogbo rẹ̀ ṣókùnkùn biribiri, ẹ̀mí Ọlọrun sì ń rábàbà lójú omi.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:1-5