Jẹnẹsisi 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

láti máa jọba lórí ọ̀sán ati òru, ati láti fi ààlà sí ààrin ìmọ́lẹ̀ ati òkùnkùn. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:13-24