Jẹnẹsisi 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ bá hu koríko jáde, oríṣìíríṣìí ohun ọ̀gbìn ati ewéko tí ń so ati oríṣìíríṣìí igi eléso tí ó ní irúgbìn ninu. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:2-17