Jakọbu 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan ẹlẹ́ran-ara bí àwa ni Elija. Ó fi tọkàntọkàn gbadura pé kí òjò má rọ̀. Òjò kò sì rọ̀ sórí ilẹ̀ fún odidi ọdún mẹta ati oṣù mẹfa.

Jakọbu 5

Jakọbu 5:8-20